Numbers 18:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Gbogbo ohun tí àwọn ọmọ Israẹli bá yà sọ́tọ̀ fún mi, tìrẹ ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun ìyasọtọ gbogbo ni Israeli ni ki o jẹ́ tirẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gbogbo nǹkan tí a yà sọ́tọ̀ fún OLÚWA ní Ísírẹ́lì jẹ́ tìrẹ.