Numbers 2:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yà Manase ni yóo pàgọ́ tẹ̀lé ẹ̀yà Efuraimu; Gamalieli, ọmọ Pedasuri, ni yóo sì jẹ́ olórí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lẹba rẹ̀ ni ki ẹ̀ya Manasse ki o wà: Gamalieli ọmọ Pedahsuru yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Manasse:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yà Mánásè ni yóò tẹ̀lé wọn. Olórí Mánásè ni Gàmálíélì ọmọ Pedasúrì.