Numbers 2:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaafa ó lé igba (32,200).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilogun o le igba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́rìndínlógún-ó-lé-igba (32,200).