Numbers 20:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà mú Aaroni ati ọmọ rẹ̀ Eleasari wá sórí òkè Hori.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mú Aaroni ati Eleasari ọmọ rẹ̀, ki o si mú wọn wá si ori-òke Hori:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mú Árónì àti ọmọ rẹ̀ Élíásárì lọ sí orí òkè Hórì.
Recommended Reading