Numbers 20:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA, gbogbo wọn sì gòkè Hori lọ níwájú gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si ṣe bi OLUWA ti fun u li aṣẹ: nwọn si gòke lọ si ori òke Hori li oju gbogbo ijọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè sì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pa láṣẹ: Wọ́n lọ sí orí òkè Hórì ní ojú gbogbo ìjọ ènìyàn.