Numbers 20:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ló dé tí ẹ fi mú àwọn eniyan OLUWA wá sinu aṣálẹ̀ yìí? Ṣé kí àwa ati àwọn ẹran ọ̀sìn wa lè kú ni?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẽha si ti ṣe ti ẹnyin fi mú ijọ OLUWA wá si aginjù yi, ki awa ati ẹran wá ki o kú nibẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ni ó dé tí o sì kó gbogbo ìjọ ènìyàn OLÚWA wá sí ihà yìí, kí àwa àti àwọn ẹran ọ̀sìn wa báà kú síbí?