Numbers 21:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò níbẹ̀, wọ́n pa àgọ́ wọn sí Obotu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Israeli si ṣi siwaju, nwọn si dó ni Obotu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tẹ̀ṣíwájú wọ́n sì péjọ sí Óbótì.