Numbers 21:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ni a ṣe kọ ọ́ sinu Ìwé Ogun OLUWA pé: “Ìlú Wahebu ní agbègbè Sufa, ati àwọn àfonífojì Arinoni,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni a ṣe wi ninu iwé Ogun OLUWA pe, Ohun ti o ṣe li Okun Pupa, ati li odò Arnoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìdí nì yìí tí ìwé ogun OLÚWA ṣe wí pé: “…Wáhébù ní Súpà, òkun pupa àti ní odò Ánónì