Numbers 21:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni àwọn ọmọ Israẹli kọ orin yìí pe: “Ẹ sun omi jáde, ẹ̀yin kànga! Ẹ máa kọrin sí i!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Israeli kọrin yi pe: Sun jade iwọ kanga; ẹ ma kọrin si i:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Ísírẹ́lì kọ orin yìí pé: “Sun jáde, ìwọ kànga! Ẹ máa kọrin nípa rẹ̀,