Numbers 22:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò, wọ́n lọ pa àgọ́ wọn sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní òdìkejì Jọdani tí ó kọjú sí Jẹriko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AWỌN ọmọ Israeli si ṣí, nwọn si dó si pẹtẹlẹ̀ Moabu li apa keji Jordani ti o kọjusi Jeriko.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rin ìrìnàjò lọ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù wọ́n sì pa ibùdó lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì tí ó kọjá lọ sí Jẹ́ríkò.