Numbers 22:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Balaki tún rán àwọn àgbààgbà mìíràn tí wọ́n pọ̀, tí wọ́n sì ṣe pataki ju àwọn ti iṣaaju lọ sí ọ̀dọ̀ Balaamu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Balaki si tun rán awọn ijoye si i, ti o si lí ọlá jù wọn lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Bálákì rán àwọn ìjòyè mìíràn tí wọ́n pọ̀ àwọn tí wọ́n sì níyì ju alákọ́kọ́ lọ.