Numbers 22:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Balaamu dáhùn pé, “Wíwá tí mo wá yìí, èmi kò ní agbára láti sọ ohunkohun bíkòṣe ohun tí OLUWA bá sọ fún mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Balaamu si wi fun Balaki pe, Kiyesi i, emi tọ̀ ọ wá: emi ha lí agbara kan nisisiyi rára lati wi ohun kan? ọ̀rọ ti OLUWA fi si mi li ẹnu, on li emi o sọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kíyèsi, èmi ti wá sọ́dọ̀ rẹ nísinsin yìí,” Bálámù fẹ̀sì pé. “Ṣùgbọ́n ṣe mo lè sọ ohunkóhun? Mo gbọdọ̀ sọ nǹkan tí OLÚWA fi sí mi lẹ́nu.”