Numbers 24:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo ṣẹgun àwọn ọ̀tá rẹ̀ ní Edomu, yóo sì gba ilẹ̀ wọn. Yóo ṣẹgun àwọn ará Seiri tí wọ́n jẹ́ ọ̀tá wọn, yóo sì gba ilẹ̀ wọn. Israẹli yóo sì máa pọ̀ sí i ní agbára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Edomu yio si di iní, Seiri pẹlu yio si di iní, fun awọn ọtá rẹ̀; Israeli yio si ṣe iṣe-agbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò borí Édómù; yóò ṣẹ́gun Ṣéérì ọ̀ta rẹ̀, ṣùgbọ́n Ísírẹ́lì yóò dàgbà nínú agbára.