Numbers 24:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti inú ìdílé Jakọbu ni àṣẹ ọba yóo ti jáde wá, yóo sì pa àwọn tí ó kù ninu ìlú náà run.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati inu Jakobu li ẹniti yio ní ijọba yio ti jade wá, yio si run ẹniti o kù ninu ilunla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olórí yóò jáde láti Jákọ́bù yóò sì pa àwọn tó ṣẹ́kù nínú ìlú náà run.”