Numbers 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn ẹ̀yin ará Keni yóo di ẹni ìparun, àwọn ará Aṣuri yóo ko yín lẹ́rú.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn a o run awọn ara Keni, titi awọn ara Aṣṣuri yio kó o lọ ni igbekùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣíbẹ̀ ẹ̀yin ará Kenítì ni yóò di píparun nígbà tí Áṣúrì bá mú yín ní ìgbékùn.”