Numbers 26:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Simeoni ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Nemueli, ìdílé Jamini, ati ìdílé Jakini;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Simeoni bi idile wọn: ti Nemueli, idile Nemueli: ti Jamini, idile Jamini: ti Jakini, idile Jakini:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ ìrán Símónì bí ìdílé wọn: ti Némúélì, ìdílé Némúélì; ti Jámínì, ìdílé Jámínì; ti Jákínì, ìdílé Jákínì;