Numbers 26:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Gadi ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Sefoni, ìdílé Hagi, ati ìdílé Ṣuni;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Gadi bi idile wọn: ti Sefoni, idile Sefoni: ti Haggi, idile Haggi: ti Ṣuni, idile Ṣuni:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Gádì bí ìdílé wọn: ti Ṣéfónì, ìdílé Ṣéfónì; ti Hágígì, ìdílé Hágígì; ti Ṣúnì, ìdílé Ṣúnì;