Numbers 26:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Juda ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Ṣela, ìdílé Peresi, ati ìdílé Sera.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Juda gẹgẹ bi idile wọn; ti Ṣela, idile Ṣela: ti Peresi, idile Peresi: ti Sera, idile Sera.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn ọmọ Júdà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣélà, ìdílé Ṣélà; ti Pérésì, ìdílé Pérésì; ti Sérà, ìdílé Ṣérà.