Numbers 26:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Isakari ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Tola, ìdílé Pua;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Issakari gẹgẹ bi idile wọn: ti Tola, idile Tola: ti Pufa, idile Pufa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Isákárì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Tólà, ìdílé Tólà; ti Púfà, ìdílé Púfà;