Numbers 26:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Josẹfu ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: Manase ati Efuraimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Josefu gẹgẹ bi idile wọn: Manasse ati Efraimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Jósẹ́fù gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn; Mánásè àti Éfúráímù: