Numbers 26:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Bẹnjamini ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Bela, ìdílé Aṣibeli, ìdílé Ahiramu;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Benjamini gẹgẹ bi idile wọn: ti Bela, idile awọn ọmọ Bela: ti Aṣbeli, idile awọn ọmọ Aṣbeli: ti Ahiramu, idile awọn ọmọ Ahiramu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn nì yí: tí Bẹ́là, ìdílé àwọn ọmọ Bẹ́là; ti Ásíbérì, ìdílé àwọn ọmọ Ásíbérì; ti Áhírámù, ìdílé àwọn ọmọ Áhírámù;