Numbers 26:42 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Dani ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Ṣuhamu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi li awọn ọmọ Dani gẹgẹ bi idile wọn: ti Ṣuhamu, idile awọn ọmọ Ṣuhamu. Wọnyi ni idile Dani gẹgẹ bi idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dánì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ṣúhámù, ìdílé àwọn ọmọ Ṣúhámù Wọ̀nyí ni ìdílé Dánì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: