Numbers 26:44 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Aṣeri ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Imina, ìdílé Iṣifi ati ìdílé Beria.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti awọn ọmọ Aṣeri gẹgẹ bi idile wọn: ti Imna, idile awọn ọmọ Imna: ti Iṣfi, idile awọn ọmọ Iṣfi: ti Beria, idile awọn ọmọ Beria.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ti àwọn ọmọ Ásérì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Ímínà, ìdílé àwọn ọmọ Ímínà; ti Íṣífì, ìdílé àwọn ọmọ Íṣífì; ti Béríà, ìdílé àwọn ọmọ Béríà;