Numbers 26:48 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Nafutali ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Jahiseeli, ìdílé Guni,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti awọn ọmọ Naftali gẹgẹ bi idile wọn: ti Jaseeli, idile awọn ọmọ Jaseeli: ti Guni, idile awọn ọmọ Guni:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ti àwọn ọmọ Náfítalì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Jásélì, ìdílé àwọn ọmọ Jásélì: ti Gúnì, ìdílé àwọn ọmọ Gúnì;