Numbers 26:57 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Lefi ní ìdílé-ìdílé nìwọ̀nyí: ìdílé Geriṣoni, ìdílé Kohati ati ìdílé Merari,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi si li awọn ti a kà ninu awọn ọmọ Lefi, gẹgẹ bi idile wọn: ti Gerṣoni, idile awọn ọmọ Gerṣoni: ti Kohati, idile awọn ọmọ Kohati: ti Merari, idile awọn ọmọ Merari.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Léfì tí a kà nínú wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: ti Gáṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gáṣónì; ti Kóhátì, ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; ti Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.