Numbers 26:58 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ìdílé tí ó wà ninu ẹ̀yà Lefi nìwọ̀nyí: ìdílé Libini, ìdílé Heburoni, ìdílé Mahili, ìdílé Muṣi ati ìdílé Kora. Kohati ni baba Amramu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi ni idile awọn ọmọ Lefi: idile awọn ọmọ Libni, idile awọn ọmọ Hebroni, idile awọn ọmọ Mali, idile awọn ọmọ Muṣi, idile awọn ọmọ Kora. Kohati si bi Amramu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Léfì; ìdílé àwọn ọmọ Líbínì, ìdílé àwọn ọmọ Hébírónì, ìdílé àwọn ọmọ Málì, ìdílé àwọn ọmọ Múṣì, ìdílé àwọn ọmọ Kórà. (Kóhátì ni baba Ámírámù,