Numbers 26:61 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nadabu ati Abihu kú nígbà tí wọ́n rúbọ sí OLUWA ninu Àgọ́ Àjọ pẹlu iná tí kò mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Nadabu ati Abihu kú, nigbati nwọn mú iná ajeji wá siwaju OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Nádábù àti Ábíhù kú, nígbà tí wọ́n rú ẹbọ níwájú OLÚWA nígbà tí wọ́n mú iná àjèjì wá.)