Numbers 27:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, ó sì fún un ní àṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi ọwọ́ rẹ̀ lé e lori, o si fi aṣẹ fun u, bi OLUWA ti wi lati ọwọ́ Mose.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó gbé ọwọ́ rẹ̀ le e, ó sì fi àṣẹ fún un gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mósè.