Numbers 27:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mose bá bá OLUWA sọ̀rọ̀ nípa wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si mú ọ̀ran wọn wá siwaju OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Mósè mú ọ̀rọ̀ wọn wá ṣíwájú OLÚWA.
Recommended Reading