Numbers 29:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose sọ gbogbo rẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si sọ fun awọn ọmọ Israeli gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA ti fi aṣẹ lelẹ fun Mose.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè sì sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbogbo ohun tí OLÚWA ti paláṣẹ fún un.