Numbers 3:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lefi ní ọmọkunrin mẹta: Geriṣoni, Kohati ati Merari, wọ́n sì jẹ́ olórí àwọn ìdílé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi si ni awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi orukọ wọn; Gerṣoni, ati Kohati, ati Merari.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Léfì: Gáṣónì, Kóhátì àti Mérárì.