Numbers 3:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Orúkọ àwọn ọmọ Merari ni Mahili ati Muṣi. Àwọn ìdílé Lefi nìwọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Merari gẹgẹ bi idile wọn; Mali, ati Muṣi. Wọnyi ni awọn idile Lefi gẹgẹ bi ile baba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìdílé Mérárì ni: Málì àti Músì. Wọ̀nyí ni ìdílé Léfì gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn: