Numbers 3:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Eliasafu ọmọ Laeli ni yóo jẹ́ olórí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Eliasafu ọmọ Laeli ni ki o ṣe olori ile baba awọn ọmọ Gerṣoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olórí àwọn ìdílé Gáṣónì ni Eliásáfì ọmọ Láélì.
Recommended Reading