Numbers 3:48 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí o sì kó owó náà fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o si fi ninu owo na, ani owo ìrapada ti o lé ninu wọn, fun Aaroni ati fun awọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Owó tí a fi ra àwọn àkọ́bí ọmọ Ísírẹ́lì tó lé yìí, ni kí o kó fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀.