Numbers 31:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi iná sun gbogbo ìlú wọn ati àwọn abúlé wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si fi iná kun gbogbo ilu wọn ninu eyiti nwọn ngbé, ati gbogbo ibudó wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n finá jó gbogbo ìlú wọn àti ibùdó wọn.