Numbers 31:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ dá àwọn obinrin wọnyi sí?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si wi fun wọn pe, Ẹ da gbogbo awọn obinrin si?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè sì bèèrè wí pé, “Ẹ̀yin ha dá gbogbo àwọn obìnrin sí bí?