Numbers 31:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan yóo mú ẹgbẹrun eniyan wá fún ogun náà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ẹ̀ya kọkan ẹgbẹrun enia, ni gbogbo ẹ̀ya Israeli, ni ki ẹnyin ki o rán lọ si ogun na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rán ẹgberún (1000) ọmọ ogun láti ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ní Ísírẹ́lì.”