Numbers 31:53 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun tí wọn kì í ṣe olórí ogun ti kó ìkógun tiwọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
(Nitoripe awọn ologun ti kó ẹrù, olukuluku fun ara rẹ̀.)
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ológun kọ̀ọ̀kan ti kó ẹrù fún ara rẹ̀.