Numbers 31:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n gbógun ti àwọn ará Midiani gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose, wọ́n sì pa gbogbo àwọn ọkunrin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwón si bá awọn ara Midiani jà, bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose; nwọn si pa gbogbo awọn ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n dojú ìjà kọ Mídíánì gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti láṣẹ fún Mósè, kí wọn sì pa gbogbo wọn.