Numbers 32:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọmọ Reubẹni ati àwọn ọmọ Gadi, tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn pupọ, rí ilẹ̀ Jaseri ati ilẹ̀ Gileadi pé ibẹ̀ dára fún àwọn ẹran ọ̀sìn wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NJẸ awọn ọmọ Reubeni ati awọn ọmọ Gadi ní ọ̀pọlọpọ ohunọ̀sin: nwọn si ri ilẹ Jaseri, ati ilẹ Gileadi, si kiyesi i, ibẹ̀ na, ibi ohunọ̀sin ni;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì àti àwọn ọmọ Gádì, tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn àti ohun ọ̀sìn rí wí pé ilé Jásérì àti Gádì dára fún ohun ọ̀sìn.