Numbers 32:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí àwọn ọmọ ogun yín sì ṣetán láti ré odò Jọdani kọjá ní àṣẹ OLUWA láti gbógun ti àwọn ọ̀tá wa títí OLUWA yóo fi pa wọ́n run,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi gbogbo nyin yio ba gòke Jordani ni ihamora niwaju OLUWA, titi yio fi lé awọn ọtá rẹ̀ kuro niwaju rẹ̀,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí gbogbo yín yóò bá lọ sí Jọ́dánì ní ìhámọ́ra níwájú OLÚWA, títí yóò fi lé àwọn ọ̀ta rẹ̀ kúrò níwájú rẹ̀.