Numbers 32:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
tí yóo sì gba ilẹ̀ náà, lẹ́yìn náà, ẹ lè pada nítorí pé ẹ ti ṣe ẹ̀tọ́ yín sí OLUWA ati sí àwọn arakunrin yín. Ilẹ̀ yìí yóo sì máa jẹ́ ìní yín pẹlu àṣẹ OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti a o si fi ṣẹ́ ilẹ na niwaju OLUWA: lẹhin na li ẹnyin o pada, ẹnyin o si jẹ́ àlailẹṣẹ niwaju OLUWA, ati niwaju Israeli; ilẹ yi yio si ma jẹ́ iní nyin niwaju OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tí a ó sì fi ṣe ilẹ̀ náà níwájú OLÚWA; ẹ̀yin lè padà tí yóò sì di òmìnira lọ́wọ́ ìdè níwájú OLÚWA àti Ísírẹ́lì. Ilẹ̀ yìí yóò sì jẹ́ ti yín níwájú OLÚWA.