Numbers 32:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Reubẹni ati Gadi sì dá Mose lóhùn, wọ́n ní,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Gadi, ati awọn Reubeni si sọ fun Mose pe, Awọn iranṣẹ rẹ yio ṣe bi oluwa mi ti fi aṣẹ lelẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Gádì àti ọmọ Rúbẹ́nì sọ fún Mósè pé, “Àwa ìránṣẹ́ rẹ yóò ṣe gẹ́gẹ́ bí OLÚWA wa ti paláṣẹ.