Numbers 32:38 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nebo, Baali Meoni (wọ́n yí orúkọ ìlú yìí pada) ati Sibima. Wọ́n sì fún àwọn ìlú tí wọn tún kọ́ ní orúkọ mìíràn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Nebo, ati Baali-meoni, (nwọn pàrọ orukọ wọn,) ati Sibma: nwọn si sọ ilu ti nwọn kọ́ li orukọ miran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
pẹ̀lú Nébò pẹ̀lú Báálì-Méónì, (“Wọ́n pàrọ̀ orúkọ wọn”) àti Síbímà. Wọ́n sì sọ ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ mìíràn.