Numbers 33:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
tí wọn ń sin òkú àwọn àkọ́bí wọn tí OLUWA pa, OLUWA fihàn pé òun ní agbára ju oriṣa àwọn ará Ijipti lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awọn ara Egipti ti nsinkú gbogbo awọn akọ́bi wọn ti OLUWA kọlù ninu wọn: lara awọn oriṣa wọn pẹlu li OLUWA ṣe idajọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tí wọ́n sì ń sin gbogbo àkọ́bí wọn, ẹni tí OLÚWA ti gbé lulẹ̀ láàrin wọn; nítorí tí OLÚWA ti mú ẹ̀san wá sórí àwọn òrìṣà wọn.