Numbers 34:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti inú ẹ̀yà Manase, a yan Hanieli ọmọ Efodu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olori awọn ọmọ Josefu: ni ẹ̀ya awọn ọmọ Manasse, Hannieli ọmọ Efodu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Háníélì ọmọ Éfódù, láti ẹ̀yà Mánásè, olórí àwọn ọmọ Jóṣẹ́fù,