Numbers 34:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti inú ẹ̀yà Sebuluni, a yan Elisafani ọmọ Parinaki.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Sebuluni, Elisafani ọmọ Parnaki.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Élísáfánì ọmọ Pánákì, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ṣébúlunì;