Numbers 34:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti inú ẹ̀yà Aṣeri, a yan Ahihudu ọmọ Ṣelomi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati olori ẹ̀ya awọn ọmọ Aṣeri, Ahihudu ọmọ Ṣelomi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhíhúdù ọmọ Ṣélómì, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì;