Numbers 34:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti ibẹ̀ lọ dé ẹnu ibodè Hamati, títí dé Sedadi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati òke Hori lọ ki ẹnyin ki o fi ori sọ ati wọ̀ Hamati; ijadelọ opinlẹ na yio si jẹ́ Sedadi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti láti orí-òkè Hórì sí Lébò Hámátì. Nígbà náà ààlà náà yóò lọ sí Sédádì,