Numbers 4:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA sọ fún Mose pé, “Ka iye àwọn ọmọ Merari ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Merari, ki iwọ ki o kà wọn gẹgẹ bi idile wọn, nipa ile baba wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ka iye àwọn ọmọ Mérárì nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn.